Ìwòye: Àwọn aládùgbò dawo lu ọkùnrin kan pa ní Ìpínlẹ̀ Ògùn; Àwọn ọlọ́pàá rí agbárí mẹ́jìdínlọ́gbọ̀n nínú igbó ní Ìpínlẹ̀ Abíà

What’s being reported
Ní ọ̀sẹ̀ yìí lórí ètò Ìwòyé: Àwọn aládùgbò dawo lu ọkùnrin kan pa ní Ìpínlẹ̀ Ògùn; Àwọn ọlọ́pàá rí agbárí mẹ́jìdínlọ́gbọ̀n nínú igbó kan ní Ìpínlẹ̀ Abíà, Ọ̀pọ̀ ènìyàn pàdánù owó ní ìlú Ọ̀ṣọ́gbò, lẹ́yìn tí wọ́n bá àwọn ẹlẹ́tàn kan ṣe.

